Àwọn Ọba Kinni 22:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Fún ọdún mẹta lẹ́yìn èyí, kò sí ogun rárá láàrin ilẹ̀ Israẹli ati ilẹ̀ Siria.

2. Nígbà tí ó di ọdún kẹta, Jehoṣafati, ọba Juda, lọ bẹ Ahabu, ọba Israẹli wò.

Àwọn Ọba Kinni 22