Àwọn Ọba Kinni 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesebẹli, aya rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Họ́wù! Ṣebí ìwọ ni ọba Israẹli, àbí ìwọ kọ́? Dìde nílẹ̀ kí o jẹun, kí o sì jẹ́ kí inú rẹ dùn, n óo gba ọgbà àjàrà Naboti fún ọ.”

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:1-11