Àwọn Ọba Kinni 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Naboti, ará Jesireeli, ní ọgbà àjàrà kan. Ní Jesireeli ni ọgbà yìí wà, lẹ́bàá ààfin Ahabu, ọba Samaria.

Àwọn Ọba Kinni 21

Àwọn Ọba Kinni 21:1-11