Àwọn Ọba Kinni 20:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu bá ranṣẹ pada sí Benhadadi ọba pé, “Mo faramọ́ ohun tí ó kọ́kọ́ bèèrè fún, ṣugbọn n kò lè gba ti ẹẹkeji yìí.”Àwọn oníṣẹ́ náà pada lọ jíṣẹ́ fún Benhadadi ọba.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:1-10