Àwọn Ọba Kinni 20:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Wolii yìí rí ọkunrin mìíràn, o sì bẹ̀ ẹ́ pé, “Lù mí.” Ọkunrin yìí lù ú, lílù náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi pa á lára.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:36-43