Àwọn Ọba Kinni 20:3 BIBELI MIMỌ (BM)

‘Tèmi ni gbogbo fadaka ati wúrà rẹ, tèmi náà sì ni àwọn tí wọ́n dára jùlọ lára àwọn aya rẹ, ati àwọn ọmọ rẹ.’ ”

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:1-9