Àwọn Ọba Kinni 20:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún tí ó tẹ̀lé e, ní ìbẹ̀rẹ̀ àkókò òjò, ó kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ, ó sì kó wọn lọ sí ìlú Afeki, láti gbógun ti àwọn ọmọ Israẹli.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:18-35