Àwọn Ọba Kinni 20:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọ̀sán, wọ́n kó ogun jáde, bí Benhadadi ọba ati àwọn ọba mejilelọgbọn tí wọ́n wà pẹlu rẹ̀ ti ń mu ọtí àmupara ninu àgọ́ wọn.

Àwọn Ọba Kinni 20

Àwọn Ọba Kinni 20:13-26