Àwọn Ọba Kinni 2:40 BIBELI MIMỌ (BM)

ó di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ kan ní gàárì, ó sì tọ Akiṣi ọba lọ sí ìlú Gati láti lọ wá àwọn ẹrú rẹ̀. Ó rí wọn, ó sì mú àwọn mejeeji pada wá sí ilé.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:36-45