Àwọn Ọba Kinni 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá ń gbọ́ ti OLUWA, OLUWA yóo pa ìlérí tí ó ṣe nípa mi mọ́, pé arọmọdọmọ mi ni yóo máa jọba ní Israẹli níwọ̀n ìgbà tí wọ́n bá pa òfin òun mọ tọkàntọkàn, pẹlu òtítọ́ inú.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:1-9