Àwọn Ọba Kinni 2:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹnaya bá lọ sinu Àgọ́ OLUWA, ó wí fún Joabu pé, “Ọba pàṣẹ pé kí o jáde.”Ṣugbọn Joabu dá a lóhùn, ó ní, “Rárá, níhìn-ín ni n óo kú sí.”Bẹnaya bá pada lọ sọ ohun tí Joabu wí fún ọba.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:27-37