Àwọn Ọba Kinni 2:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Joabu gbọ́ ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó sá lọ sinu Àgọ́ OLUWA, ó sì di ìwo pẹpẹ mú, nítorí pé lẹ́yìn Adonija ni ó ti wà tẹ́lẹ̀ rí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò sí lẹ́yìn Absalomu.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:26-38