Àwọn Ọba Kinni 2:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni ọba bá pàṣẹ fún Bẹnaya, pé kí ó lọ pa Adonija, ó bá jáde, ó sì lọ pa á.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:21-31