Àwọn Ọba Kinni 2:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni bá búra lórúkọ OLUWA pé, kí Ọlọrun pa òun bí òun kò bá pa Adonija nítorí ọ̀rọ̀ yìí.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:19-29