Àwọn Ọba Kinni 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogoji ọdún ni ó fi jọba Israẹli. Ó ṣe ọdún meje lórí oyè ní Heburoni, ó sì ṣe ọdún mẹtalelọgbọn ní Jerusalẹmu.

Àwọn Ọba Kinni 2

Àwọn Ọba Kinni 2:1-15