Àwọn Ọba Kinni 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesebẹli bá rán oníṣẹ́ kan sí Elija pẹlu ìbúra pé, “Kí àwọn oriṣa pa mí, bí n kò bá pa ọ́ ní ìwòyí ọ̀la, bí o ti pa àwọn wolii Baali.”

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:1-6