Àwọn Ọba Kinni 19:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA dá a lóhùn pé, “Pada lọ sinu aṣálẹ̀ ẹ̀bá Damasku. Nígbà tí o bá dé ibẹ̀, fi àmì òróró yan Hasaeli ní ọba Siria.

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:9-20