Àwọn Ọba Kinni 19:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Elija gbọ́ ohùn náà, ó fi ẹ̀wù rẹ̀ bojú, ó jáde, ó sì dúró ní ẹnu ọ̀nà ihò àpáta náà. Ohùn kan bi í pé, “Elija, kí ni ò ń ṣe níhìn-ín?”

Àwọn Ọba Kinni 19

Àwọn Ọba Kinni 19:6-18