Àwọn Ọba Kinni 18:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sọ fún iranṣẹ rẹ̀ pé kí ó lọ wo apá ìhà òkun.Iranṣẹ náà lọ, ó sì pada wá, ó ní, òun kò rí nǹkankan. Elija sọ fún un pé, “Tún lọ ní ìgbà meje.”

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:40-46