Àwọn Ọba Kinni 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija tún sọ fún wọn pé, “Èmi nìkan ṣoṣo ni wolii OLUWA tí ó ṣẹ́kù, ṣugbọn àwọn wolii oriṣa Baali tí wọ́n wà jẹ́ aadọtalenirinwo (450).

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:17-32