Àwọn Ọba Kinni 18:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahabu bá ranṣẹ pé gbogbo àwọn ọmọ Israẹli, ati àwọn wolii oriṣa Baali, pé kí wọ́n pàdé òun ní orí òkè Kamẹli.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:19-30