Àwọn Ọba Kinni 18:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àbí o kò gbọ́ nígbà tí Jesebẹli ń pa àwọn wolii OLUWA, pé mo kó ọgọrun-un ninu wọn pamọ́ sinu ihò àpáta meji, mo kó araadọta sinu ihò kọ̀ọ̀kan, mo sì ń fún wọn ní oúnjẹ ati omi.

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:10-18