Àwọn Ọba Kinni 18:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn ọjọ́ pípẹ́, ní ọdún kẹta tí ọ̀dá ti dá, OLUWA sọ fún Elija pé, “Lọ fi ara rẹ han Ahabu ọba, n óo sì rọ̀jò sórí ilẹ̀.”

Àwọn Ọba Kinni 18

Àwọn Ọba Kinni 18:1-6