Àwọn Ọba Kinni 17:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Dìde nisinsinyii, kí o lọ sí ìlú Sarefati, ní agbègbè Sidoni, kí o sì máa gbé ibẹ̀. Mo ti pàṣẹ fún opó kan níbẹ̀ láti máa fún ọ ní oúnjẹ.”

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:1-15