Àwọn Ọba Kinni 17:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹyẹ ìwò ń gbé oúnjẹ ati ẹran wá fún un ní ojoojumọ, ní àràárọ̀ ati ní ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́, ó sì ń mu omi odò náà.

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:5-13