Àwọn Ọba Kinni 17:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Elija gbé ọmọ náà sọ̀kalẹ̀ pada sọ́dọ̀ ìyá rẹ̀, ó sì wí fún un pé, “Wò ó! Ọmọ rẹ ti sọjí.”

Àwọn Ọba Kinni 17

Àwọn Ọba Kinni 17:19-24