Àwọn Ọba Kinni 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Baaṣa kú, wọ́n sì sin ín sí Tirisa. Ela ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:5-16