Àwọn Ọba Kinni 16:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà, ó tún ṣe oriṣa Aṣera kan. Ahabu ṣe ohun tí ó bí OLUWA Ọlọrun Israẹli ninu ju gbogbo àwọn ọba Israẹli tí wọ́n jẹ ṣáájú rẹ̀ lọ.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:23-34