Àwọn Ọba Kinni 16:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni pé, gbogbo àìdára tí Ahabu ọba ṣe bíi ti Jeroboamu, ọmọ Nebati, kò burú tó, ó tún lọ fẹ́ Jesebẹli ọmọbinrin Etibaali, ọba Sidoni, ó sì ń bọ oriṣa Baali.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:26-34