Àwọn Ọba Kinni 16:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo pa ìwọ ati ìdílé rẹ rẹ́. Bí mo ti ṣe ìdílé Jeroboamu, bẹ́ẹ̀ ni n óo ṣe ìdílé tìrẹ náà.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:1-4