Àwọn Ọba Kinni 16:19 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá, tí ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA, tí ó tọ ọ̀nà tí Jeroboamu tọ̀, ati fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá: tí ó mú kí àwọn ọmọ Israẹli náà dẹ́ṣẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:10-22