Àwọn Ọba Kinni 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹtadinlọgbọn tí Asa jọba ní Juda, Simiri gorí oyè ní Tirisa, ó sì jọba Israẹli fún ọjọ́ meje. Ní àkókò yìí àwọn ọmọ ogun Israẹli gbógun ti ìlú Gibetoni ní ilẹ̀ Filistia.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:7-22