Àwọn Ọba Kinni 16:13 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí Baaṣa ati Ela ọmọ rẹ̀ dá ati èyí tí wọ́n mú kí Israẹli dá, tí wọ́n mú kí OLUWA Ọlọrun Israẹli bínú nítorí oriṣa wọn.

Àwọn Ọba Kinni 16

Àwọn Ọba Kinni 16:6-15