Àwọn Ọba Kinni 15:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Abijamu jáde láyé, wọ́n sì sin ín ní ìlú Dafidi, Asa, ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:1-9