Àwọn Ọba Kinni 15:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ogun tí ó wà láàrin Rehoboamu ati Jeroboamu tún wà bẹ́ẹ̀ ní gbogbo ìgbà tí Abijamu wà lórí oyè.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:1-8