Àwọn Ọba Kinni 15:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹta tí Asa, ọba Juda, gorí oyè, ni Baaṣa, ọmọ Ahija, gorí oyè, ní ìlú Tirisa, ó sì di ọba gbogbo Israẹli. Ó jọba fún ọdún mẹrinlelogun.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:28-34