Àwọn Ọba Kinni 15:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí Jeroboamu ṣe ohun tí ó bí OLUWA Ọlọrun Israẹli ninu: ó dẹ́ṣẹ̀, ó sì mú kí Israẹli náà dẹ́ṣẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:21-34