Àwọn Ọba Kinni 15:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹta tí Asa gorí oyè ní ilẹ̀ Juda, ni Baaṣa pa Nadabu. Baaṣa gorí oyè dípò Nadabu, ó sì di ọba ilẹ̀ Israẹli.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:25-33