Àwọn Ọba Kinni 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Benhadadi ọba gba ohun tí Asa wí, ó sì rán àwọn ọ̀gágun rẹ̀ láti lọ gbógun ti àwọn ìlú ńláńlá Israẹli. Wọ́n gba ìlú Ijoni ati Dani, Abeli Beti Maaka, ati gbogbo agbègbè Kineroti, pẹlu gbogbo agbègbè Nafutali.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:11-30