Àwọn Ọba Kinni 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn aṣẹ́wó ọkunrin tí wọ́n wà ní ojúbọ àwọn oriṣa káàkiri ní ilẹ̀ Juda, ni Asa lé jáde kúrò ni ilẹ̀ náà; ó sì kó gbogbo àwọn oriṣa tí àwọn baba ńlá rẹ̀ ti ṣe dànù.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:6-14