Àwọn Ọba Kinni 15:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdún mọkanlelogoji ni ó fi jọba ní Jerusalẹmu. Maaka ọmọ Absalomu ni ìyá baba rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 15

Àwọn Ọba Kinni 15:6-16