Àwọn Ọba Kinni 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn o ti dá ọpọlọpọ ẹ̀ṣẹ̀ burúkú ju ti àwọn tí wọ́n jọba ṣáájú rẹ lọ. O yá ère, o sì dá oniruuru oriṣa láti máa sìn, o mú mi bínú, o sì ti pada lẹ́yìn mi.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:1-12