Àwọn Ọba Kinni 14:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó gbogbo ìṣúra tí ó wà ninu ilé OLUWA ati ti ààfin ọba pátá; gbogbo apata wúrà tí Solomoni ṣe ni ó kó lọ pẹlu.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:17-31