Àwọn Ọba Kinni 14:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin tí wọ́n sọ ara wọn di aṣẹ́wó ní ojúbọ àwọn oriṣa náà sì pọ̀ ní ilẹ̀ náà. Gbogbo ohun ìríra tí àwọn orílẹ̀-èdè tí OLUWA lé jáde fún àwọn ọmọ Israẹli ń ṣe, ni àwọn náà ń ṣe.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:21-31