Àwọn Ọba Kinni 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀yà Juda ṣẹ̀ sí OLUWA, wọ́n sì ṣe ohun tí ó mú un bínú lọpọlọpọ ju gbogbo àwọn baba ńlá wọn lọ.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:16-29