Àwọn Ọba Kinni 14:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeroboamu jọba fún ọdún mejilelogun. Lẹ́yìn náà, ó kú, wọ́n sì sin ín. Nadabu, ọmọ rẹ̀ sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:19-29