Àwọn Ọba Kinni 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ni yóo ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, wọn yóo sì sin ín, nítorí òun nìkan ni wọ́n óo sin ninu ìdílé Jeroboamu, nítorí òun nìkan ni inú OLUWA Ọlọrun Israẹli dùn sí.

Àwọn Ọba Kinni 14

Àwọn Ọba Kinni 14:11-23