Àwọn Ọba Kinni 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bá sọ fún wolii náà pé, “Jẹ́ kí á lọ sí ilé mi kí o lọ jẹun, n óo sì fún ọ ní ẹ̀bùn fún ohun tí o ṣe fún mi.”

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:1-11