Àwọn Ọba Kinni 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Pẹpẹ náà wó lulẹ̀, eérú orí rẹ̀ sì fọ́n dànù gẹ́gẹ́ bí wolii náà ti sọtẹ́lẹ̀ ní orúkọ OLUWA.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:1-7