Àwọn Ọba Kinni 13:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá pe àwọn ọmọ rẹ̀, ó wí fún wọn pé, “Ẹ bá mi di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ mi ní gàárì.” Wọ́n sì bá a di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ní gàárì.

Àwọn Ọba Kinni 13

Àwọn Ọba Kinni 13:22-29